HYMN – SE MI NI ORI (BABA) NINU ILE BABA MI

SE MI NI ORI (BABA) NINU ILE BABA MI
Composed by Z. A. Ogunsanya, 1/4/2018. While leading the church in a prayerabout how God will make each of us the solution provider in each of our father’s houses

1. Se mi ni ori (Baba) ninu ile Baba mi
Ma je k’emi d’iru, adura mi niyen.

Egbe: Wa mu se (Baba), adura mi niyen
Tete mu un se (Baba), adura mi niyen.

2. Gbo adura mi, (Baba) ti mo ngba n’igba gbogbo
Ma je k’emi kuna, adurami niyen.

3. Se ‘yanu fun mi, (Baba) n’ipa t’ara at’emi
Ma je k’ibi ba mi, adurami niyen.

4. F’ese mi mule (Baba) ninu ile Re Jesu
Ma k’emi w’eyin, adurami niyen.

5. Pami ni erin, (Baba) n’igba gbogbo l’aye ni
Ma je k’emi sokun, adurami niyen.

6. Fun mi n’igboya (Baba) pelu ifokanbale
Ma je k’emi foya, adurami niyen.

7. Di mi mu d’opin, (Baba) l’ona ile ologo
Ma je k’emi segbe, adurami niyen.