HYMN – OLORUN WA A M’OPE WA FUN O

OLORUN WA A M’OPE WA FUN O
Composed by Z. A. Ogunsanya, 21/4/2019. In the church, during Easter confab.

1. Olorun wa a m’ope wa fun O
Olorun wa a wa gbe O ga o
Olorun orun a wa yin O l’ogo /2ice.

Egbe: A wa gbe o ga /3ice.
Atobijulo a wa yin O l’ogo /2ice.

2. Fun ife Re a m’ope wa fun O
Fun ‘dariji a wa gbe O ga o
Fun irapada a wa yin O l’ojo /2ice.

3. Fun igbala a m’ope wa fun O
Fun ‘wenumo a wa gbe O ga o
Fun agbara Re a wa yin O l’ojo /2ice.

4. Fun ore Re a m’ope wa fun O
Fun anu Re a wa gbe O ga o
Fun iranwo Re a wa yin O l’ojo /2ice.

5. Fun abo Re a m’ope wa fun O
Fun ‘pese Re a wa gbe O ga o
Fun ibukun Re a wa yin O l’ojo /2ice.

6. Fun ise wa a m’ope wa fun O
Fun obi wa a wa gbe O ga o
Fun idile wa a wa yin O l’ojo /2ice.

7. F’ore ofe a m’ope wa fun O
Fun ayo Re a wa gbe O ga o
Fun itoju Re a wa yin O l’ojo /2ice.

8. Fun idasi a m’ope wa fun O
Fun iwosan a wa gbe O ga o
Fun atileyin a wa yin O l’ojo /2ice.

9. Fun oni wa a m’ope wa fun O
Fun ola wa a wa gbe O ga o
Fun ayeraye a wa yin O l’ojo /2ice.