HYMN – OJU KO NI TI AWA OMO OLORUN

OJU KO NI TI AWA OMO OLORUN
Composed by Z. A. Ogunsanya, 29/6/2019. On the way from Benin to Asaba during missionary journey.

Egbe: Oju ko ni ti awa omo Olorun
           Ninu Jesu ti a wa yi
          Aseyori wa daju.

1. Bi aye ba un feju
Bi Esu ba un hale
Ipa won ko le ka wa
Jesu l’atileyin wa.

2. Bi aisan ba yoju
Bi iku ba kan ‘lekun
Eru kan ko si fun wa
Jesu ni ilera wa.

3. Bi o se l’oju aye
B’o si se l’oju aye
Ni isoro ti dide
Jesu ni isegun wa.

4. Ninu irin ajo wa
Ibi kan ko ni ba wa
Ewu kan ki yo wu wa
Jesu ni alabo wa.