HYMN – IYANU NI O O BABA MI

IYANU NI O O BABA MI

Composed by Z. A. Ogunsanya, 7/8/2019. On my bed early in the
morning, the day confab was to start.

1. Iyanu ni O o Baba mi /2ice.
Oba ti O pin okun niya
Iyanu ni O o Baba lori isoro
Oba ti O gba okan mi la
Iyanu ni O o Baba ninu okan mi.

Egbe: Iyanu ni, iyanu ni
Iyanu ni O o Baba ninu aye mi.

2. Iyanu ni O o Baba mi /2ice.
Oba t’O wo odi Jeriko
Iyanu ni O o Baba lori idena
Oba t’O yo mi ninu ofin
Iyanu ni O o Baba ninu aye mi.

3. Iyanu ni O o Baba mi /2ice.
Oba ti O fun Hanna l’omo
Iyanu ni O o Baba lori aini
Oba ti O bukun aye mi
Iyanu ni O o Baba ninu ebi mi.

4. Iyanu ni O o Baba mi /2ice.
Oba t’O ji oku Lasaru
Iyanu ni O o Baba ni ori iku
Oba ti O mu mi larada
Iyanu ni O o Baba ninu ara mi.

5. Iyanu ni O o Baba mi /2ice.
Oba t’O goke lo si orun
Iyanu ni O o Baba ni ona gbogbo
Oba ti yo mu mi de orun
Iyanu ni O o Baba ninu okan mi.