ILEKUN OGBON RE BABA SI S’ILE FUN MI
Composed by Z. A. Ogunsanya, 1/2/2019.
- Ilekun ogbon Re Baba si s’ile fun mi
Ilekun imo Re Baba si s’ile fun mi
Ilekun oye Re Baba si fun mi k’o gboro /2ice.
Egbe: Baba, s’ilekun Re fun mi
Tete si k’o gboro.
-
Ilekun ilera Baba si s’ile fun mi
Ilekun ipese Baba si s’ile fun mi
Ilekun akojo Baba si fun mi k’o gboro /2ice. -
Ilekun agbara Baba si s’ile fun mi
Ilekun isegun Baba si s’ile fun mi
Ilekun igbega Baba si fun mi k’o gboro /2ice. -
Ilekun abo Re Baba si s’ile fun mi
Ilekun ebun Re Baba si s’ile fun mi
Ilekun ayo Re Baba si fun mi k’o gboro /2ice. -
Ilekun adura Baba si s’ile fun mi
Ilekun oro Re Baba si s’ile fun mi
Ilekun ife Re Baba si fun mi k’o gboro /2ice. -
Ilekun owo Re Baba si s’ile fun mi
Ilekun itura Baba si s’ile fun mi
Ilekun isimi Baba si fun mi k’o gboro /2ice. -
Ilekun Emi Re Baba si s’ile fun mi
Ilekun ile Re Baba si s’ile fun mi
Ilekun orun Re Baba si fun mi k’o gboro /2ice.