HALLELUJAH L’O YE O BABA
- Ha-lle-luya, l’a mu wa fun O
Nitori ise iyanu Re, (Baba) ti O un se l’aye wa. -
Ha-lle-luya, l’orin wa titi
N’igba gbogbo l’ojo aye wa, (Baba) l’a o fi ma gbe O ga. -
Ha-lle-luya, l’osan at’oru
N’ile ati ni irin ajo, (Baba) l’awa yo ma ko si O. -
Ha-lle-luya, l’aye at’orun
Ati ni gbogbo ayeraye, (Baba) l’awa yo ma gbe O ga.
Z. A. Ogunsanya, 20/12/2018. Early in the morning in the church,
as the hour of miracle was about to start.