F’IRE BA MI PADE L’OJO ONI OLUWA
Composed by Z. A. Ogunsanya, 11/4/2018. As I woke up in the morning still on my bed.
-
F’ire ba mi pade l’ojo oni Oluwa
F’ayo ba mi pade l’ojo oni Oluwa
Je k’emi ko s’aseyori ni ona gbogbo /2ice.
Amin, ni oruko Jesu /2ice. -
F’iyanu Re han mi l’ojo oni Oluwa
F’agbara Re han mi l’ojo oni Oluwa
Je k’aye mi k’o gun rege ni ona gbogbo /2ice.
Amin, ni oruko Jesu /2ice. -
Ma je k’ebi pa mi l’oJo oni Oluwa
Ma je k’iya je mi l’ojo oni Oluwa
Je ki okan mi k’o bale ni igba gbogbo /2ice.
Amin, ni oruko Jesu /2ice. -
Ma je k’emi subu l’oJo oni Oluwa
Ma je k’ese mi ye l’ojo oni Oluwa
Je k’emi le duro sinsin titi de opin /2ice.
Amin, ni oruko Jesu /2ice.