E SE O BABA OPE YE O O
Composed by Z. A. Ogunsanya, 13/1/2019.
Egbe: E se o Baba /3ice.
Ope ye O o.
-
A mu ope wa
Wa fun O Baba
Wa fun O Baba Mimo
O pe ye O o. -
A mu ope wa
Wa fun O Omo
Wa fun Ologbala
O pe ye O o. -
A mu ope wa
Wa fun O Emi
Wa fun O Emi Mimo
O pe ye O o.