E JE K’A JO YIN OLUWA
- E je k’a jo yin Oluwa (E je k’a jo yin Oluwa)
Oba ti O dariji wa (Oba ti O dariji wa)
E je k’a jo yin Oluwa (E je k’a jo yin Oluwa)
Oba ti O gb’okan wa la (Oba ti O gb’okan wa la).Egbe: Baba wa (Baba wa)
Ti nmbe l’orun (Ti nmbe l’orun)
E se o (E se o). -
E je k’a k’orin s’Oluwa (E je k’a k’orin s’Oluwa)
Oba ti O nfun wa l’ayo (Oba ti O nfun wa l’ayo)
E je k’a k’orin s’Oluwa (E je k’a k’orin s’Oluwa)
Oba t’O nf’okan wa bale (Oba t’O f’okan wa bale). -
E je k’a f’ijo f’Oluwa (E je k’a f’ijo f’Oluwa)
Oba ti O ngb’adura wa (Oba ti O ngb’adura wa)
E je k’a f’ijo f’Oluwa (E je k’a f’ijo f’Oluwa)
Oba ti O nsure fun wa (Oba ti O nsure fun wa). -
E je k’a f’ogo f’Oluwa (E je k’a f’ogo f’Oluwa)
Oba ti O nd’abo bo wa (Oba ti O nd’abo bo wa)
E je k’a f’ogo f’Oluwa (E je k’a f’ogo f’Oluwa)
Oba ti O npese fun wa (Oba ti O npese fun wa). -
E je k’a f’ope f’Oluwa (E je k’a f’ope f’Oluwa)
Oba ti O nsegun fun wa (Oba ti O nsegun fun wa)
E je k’a f’ope f’Oluwa (E je k’a f’ope f’Oluwa)
Oba ti O nda wa l’are (Oba ti O nda wa l’are). -
E je k’a f’ola f’Oluwa (E je k’a f’ola f’Oluwa)
Oba ti O nranwa l’owo (Oba ti O nranwa l’owo)
E je k’a f’ola f’Oluwa (E je k’a f’ola f’Oluwa)
Oba ti O nsure fun wa (Oba ti O nsure fun wa). -
E je k’a romo Oluwa (E je k’a romo Oluwa)
Oba ti ko je k’a subu (Oba ti ko je k’a subu)
E je k’a romo Oluwa (E je k’a romo Oluwa)
Oba ti yo gbe wa de’le (Oba ti yo gbe wa de’le).
Z. A. Ogunsanya, 3/10/2018. I heard myself humming this in my sleep, without preparing to sing.