BABA MIMO MO WA DUPE
Egbe: Baba Mimo mo wa dupe
Olorun mi mo wa yin O
Oluwa E se, mo wa dupe o.
- Fun ti Jesu mo wa dupe
F’Emi Mimo mo wa yin O
Baba l’oke, mo wa dupe o. -
Fun t’igbala mo wa dupe
Fun ‘wenumo mo wa yin O
Fun t’agbara, mo wa dupe o. -
Fun Bibeli mo wa dupe
Fun t’adura mo wa yin O
F’orin mimo, mo wa dupe o. -
Fun t’ipese mo wa dupe
Fun t’iranwo mo wa yin O
Fun t’abo Re, mo wa dupe o. -
Fun t’obi mi mo wa dupe
Fun t’ebi mi mo wa yin O
Fun t’ijo mi, mo wa dupe o. -
Fun t’ilera mo wa dupe
Fun t’ayo Re mo wa yin O
Fun ‘le ogo, mo wa dupe o. -
Fun oni yi mo wa dupe
Fun ola mi mo wa yin O
F’ayeraye, mo wa dupe o.
Z. A. Ogunsanya, 16/11/2018. 181116 Why meditating in my room,
in the afternoon, my heart began to hum.