HYMN – BABA MI TI NBE L’ORUN, EYIN L’O NRANMILOWO

BABA MI TI NBE L’ORUN, EYIN L’O NRANMILOWO
Composed by Z. A. Ogunsanya, 27/6/2018. In my bathroom in the morning.

  1. Baba mi ti nbe l’orun (Baba mi ti nbe l’orun).
    Eyin l’O nranmilowo (Eyin l’O nranmilowo)
    Eyin l’O nf’agbara kun mi (Eyin l’O nf’agbara kun mi)
    Eyin l’O nbukun mi o (Eyin l’O nbukun mi o)
    E tun bo bukun fun mi (E tun bo bukun fun mi)
    K’oju ma ti mi rara (K’oju ma ti mi rara)
    Rara /8x (Rara /8x)
    Rara raraaaa.

  2. Baba mi ti nbe l’orun (Baba mi ti nbe l’orun)
    Eyin ni mo gb’oju le (Eyin ni mo gb’oju le)
    Eyin ni mo f’eyin mi ti (Eyin ni mo f’eyin mi ti)
    Eyin l’O nd’abo bo mi (Eyin l’O nd’abo bo mi)
    E tun bo d’abo bo mi (E tun bo d’abo bo mi)
    K’ewu ma wu mi rara (K’ewu ma wu mi rara)
    Rara /8x (Rara /8x)
    Rara raraaaa.

  3. Baba mi ti nbe l’orun (Baba mi ti nbe l’orun)
    Eyin l’O nsanu fun mi (Eyin l’O nsanu fun mi)
    Eyin l’O ngbo adura mi (Eyin l’O ngbo adura mi)
    Eyin l’O nyamilenu (Eyin l’O nyamilenu)
    E tun bo yamilenu (E tun bo yamilenu)
    K’aye mi le gun rege (K’aye mi le gun rege)
    Rege /8x (Rege /8x)
    Rere referee.

  4. Baba mi ti nbe l’orun (Baba mi ti nbe l’orun)
    Eyin l’O gb’okan mi la (Eyin l’O gb’okan mi la)
    Eyin l’O so mi di mimo (Eyin l’O so mi di mimo)
    Eyin l’O mu mi duro (Eyin l’O mu mi duro)
    E tun bo mu mi duro (E tun bo mu mi duro)
    K’emi ma se ku s’ona (K’emi ma se ku s’ona)
    Rara /8x (Rara /8x)
    Rara raraaaa.