BABA MI NI K’O GBA FUN
Composed by Z. A. Ogunsanya, 26/5/2019. As I was going to church on Sunday morning.
Ibere: Baba mi ni k’o gba fun )
(Baba mi ni k’o gba fun Esu o) /2ice.
Gbogbo ibi t’o ni l’ero fun mi)
Baba mi ni ko gba fun rara )/2ice.
1. O fe k’ori maa fo mi (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’edo maa dun mi (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’oju mi k’o ti fo (Baba mi ni k’o gba fun rara)
Baba mi ko le gba o (Baba mi k’o le gba fun rara)
2. O fe k’ile mi ko daru (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’ibi maa bami (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’omo mi k’o seku (Baba mi ni k’o gba fun rara)
Baba mi ko le gba o (Baba mi k’o le gba fun rara).
3. O fe k’ise mi k’o ti bo (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’emi d’atoroje (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’aye mi d’ojuru (Baba mi ni k’o gba fun rara)
Baba mi ko le gba o (Baba mi k’o le gba fun rara).
3. O fe k’emi k’o lo se’so (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’emi s’egbe awo (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’emi d’oniyeye (Baba mi ni k’o gba fun rara)
Baba mi ko le gba o (Baba mi k’o le gba fun rara).
4. O fe k’emi d’peyinda (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’emi tun maa d’ese (Baba mi ni k’o gba fun rara)
O fe k’emi segbe m’aye (Baba mi ni k’o gba fun rara)
Baba mi ko le gba o (Baba mi k’o le gba fun rara).
Like this:
Like Loading...