A F’OPE FUN O, O BABA WA
Composed by Z. A. Ogunsanya, 13/06/2015
1. A f’ola fun O o Baba wa
A f’iyin fun O o Baba wa
A f’ogo fun O o Baba wa
Te’wo gb’ope wa o Baba wa
Egbe: Eredi adura wa l’eyi
Tete ba wa se o
K’a maa jo o, ka maa yo o)
Ka maa f’ogo fun Baba ) 2ice
2. F’agbara fun wa o Baba wa
F’ilera fun wa o Baba wa
F’itura fun wa o Baba wa
Si fun wal’ayo o Baba wa
3. Se’yanu fun wa o Baba wa
Si sure fun wa o Baba wa
S’atilehinwa o Baba wa
Si gbe was’oke o Baba wa
4. Wa da wal’ohun o Baba wa
Wa pese fun wa o Baba wa
Wa f’aabo bo wa o Baba wa
K’a ma k’agbako o Baba wa
5. Wa s’aanu fun wa o Baba wa
Wa ran wa lowo o Baba wa
Wa gbe wa ni’ja o Baba wa
Wa segun fun wa o Baba wa
Amin o.