O SEUN JESU, O SEUN
Composed by Z. A. Ogunsanya Date: 4/3/2016
O seun Jesu, O seun, 2ice
Mo yin O, mo juba Re
O seun Jesu o seun.
OPE, OPE, OPE
Composed by Z. A. Ogunsanya Date: 15/09/2016
Ope, ope, ope
Ola, ola, ola
Iyin l’oye Jesu
Oba wa Oloore.
OPE, OPE, OLA, OLA, OGO, OGO
Ope, Ope, ola, ola, ogo, ogo
Iyin l’o ye O o Baba Ologojulo.
OPE, OLA, OGO L’O YE O O BABA.
Ope, ola, ogo l’o ye O o Baba.
Ope Re ni mo mu wa
OPE L’O YE BABA
Composed by Z. A. Ogunsanya Date:16/01/2016
Ope, ope, ope l’o ye Baba /2ice
Fun ore Re ninu aye wa ope l’o ye Baba /2ice.
OPE L’O YE O BABA ALEWILESE
Composed by Z. A. Ogunsanya Date:27/02/2017
Ope l’o ye O Baba alewilese
Fun ore Re ninu aye mi
Ope, Ope, Ope l’o ye O.
OPE YE BABA
Composed by Z. A. Ogunsanya Date:20/01/2017
As I was about to leave my office
1.Ope ye Baba
Ope ye Omo
Ope y’Emi Mimo
Ope ye Metalokan.
- Ogo ye Baba
- Ola ye Baba
- Iyin ye Baba
- Emi yin Baba
- Mo gbe Baba ga
- Awa yin Baba
- A gbe Baba ga
- E wa yin Baba
- E gbe Baba ga
SE ‘YANU FUN MI O
Composed by Z. A. Ogunsanya Date:15/09/2016
Se ‘yanu fun mi o
K’oju ma ti mi o
Olorun iyanu.
WA GBO EBE MI OLUWA
Composed by Z. A. Ogunsanya Date:05/08/2016
On my bed, 03:30 am.
Wa gbo ebe mi Oluwa.
Jowo ma se je ki oju ti mi.