CHORUS – OBA ON’ISE ARA, L’OLORUN WA Hymn, Chorus & Worship - Baba oni'se ara l' Olorun wa OBA ON’ISE ARA, L’OLORUN WA Composed by Z. A. Ogunsanya Date: 20/03/2017. Oba On’ise ara, l’Olorun wa Oba On’ise iyanu, l’Olorun wa Ko ma s’ohun ti agbara Re ko ka (l’aye wa) On’ise ara, l’Olorun wa. Share this:TwitterFacebookLike this:Like Loading...