SE’YANU, OLU-ORUN SE’YANU FUN MI
Composed by Z. A. Ogunsanya Date: 23/3/2017.

Egbe: Se’yanu, Olu-orun se’yanu fun mi
Se’yanu, Baba mi tun se’yanu fun mi
Odo Re nikan, l’ati le ri’yanu otito (gba o Baba)
Se’yanu, Baba mi tun se’yanu fun mi.

 1. L’ori aye mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori okan mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori ile mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori ise mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  Odo Re nikan, ni mo ti ri ifokanbale
  Se’yanu, Eleda mi se’yanu fun mi.

 2. L’ori ebi mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori obi mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori aya (oko) mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori omo mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  Odo Re nikan, ni mo fi igbekele mi si
  Se’yanu, Atobiju se’yanu fun mi.

 3. L’ori jije, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori mimu, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori nina, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ori lilo, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  Odo Re nikan, ni mo ti ni ipese kikun
  Se’yanu, Oga-ogo se’yanu fun mi.

 4. L’arin ijo Re, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’arin awujo, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  N’irin ajo mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’oju ala mi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  Odo Re nikan, ni mo ti ni abo t’o daju
  Se’yanu, Oba-iye se’yanu fun mi.

 5. Nipa t’emi, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’enu ise Re, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’enu adura, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  L’ona tooro, se’yanu fun mi, Baba se’yanu
  Odo Re nikan, ni mo n’ireti ayeraye
  Se’yanu, Alagbara se’yanu fun mi.