HYMN – JE K’O ROMILORUN BABA LATI GBORAN SI O

JE K’O ROMILORUN BABA LATI GBORAN SI O
Composed by Z. A. Ogunsanya Date: 23/12/2017. Sunday, during worship time.

 1. Je k’o romilorun Baba lati gboran si O
  Je k’o romilorun Baba lati se ife Re
  Je k’o romilorun Baba lati j’eni mimo.

Egbe: Amin o; je k’o romilorun Baba /3ice.

 1. Je k’o romilorun Baba lati ka Bibeli
  Je k’o romilorun Baba lati kun f’adura
  Je k’o romilorun Baba lati Jere okan.

 2. Je k’o romilorun Baba lati j’olotito
  Je k’o romilorun Baba lati sa fun ‘binu
  Je k’o romilorun Baba lati segun Esu.

 3. Je k’o romilorun Baba lati wulo fun O
  Je k’o romilorun Baba lati san ‘damewa
  Je k’o romilorun Baba lati j’onirele.

 4. Je k’o romilorun Baba l’oju ona tooro
  Je k’o romilorun Baba lati sin O d’opin
  Je k’o romilorun Baba lati ba O j’oba.