IYANU NI O, JESU IYANU NI O O
Composed by Z. A. Ogunsanya Date: 22/7/2017.
Egbe: Iyanu ni O o )
Jesu Iyanu ni O o) /2ice.
-
Iwo t’O da aye, ti O da orun
Iwo l’O gbamila
Iyanu ni O, Jesu Iyanu ni O o. -
Iwo t’O wa mi ri, nnu ira ese
Iwo n’ireti mi
Iyanu ni O, Jesu Iyanu ni O o. -
Iwo t’O da gbogbo, erupe ile
Iwo l’O nbukun mi
Iyanu ni O, Jesu Iyanu ni O o. -
Iwo ti O ti ku, t’O tun jinde
Iwo l’O wo mi san
Iyanu ni O, Jesu Iyanu ni O o. -
Iwo t’O se t’emi, ni aseyori
Iwo l’emi yo sin
Iyanu ni O, Jesu Iyanu ni O o. -
Iwo t’O goke lo, si oke orun
Iwo yo pada wa
Iyanu ni O, Jesu Iyanu ni O o. -
Iwo t’O damisi, di ojo oni
Iwo l’ayeraye
Iyanu ni O, Jesu Iyanu ni O o.