IYANU L’E SE L’AYE MI, IYANU L’E SE
Composed by Z. A. Ogunsanya Date: 3/11/2017.
-
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se /2ice.
Oba t’O gbamila, Ti O tun wo mi san
T’O f’okan mi bale
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se. -
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se /2ice.
Oba t’O we mi mo, T’O f’agbara kun mi
T’O tun segun fun mi
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se. -
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se /2ice.
Oba t’O ngbadura, fun mi l’oke orun
T’O un ko’le de mi
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se. -
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se /2ice.
Oba t’O damisi, Ti O tun gbemiro
T’O si fun mi l’ayo
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se. -
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se /2ice.
Oba t’O ntoju mi, T’O un s’amonami
T’O tun ndurotimi
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se. -
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se /2ice.
Oba t’O sure fun, gbogbo idile mi
T’O tun ndabo bo wa
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se. -
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se /2ice.
Oba t’O goke lo, Ti Yo tun padawa
L’ati mu mi rele
Iyanu l’E se l’aye mi, iyanu l’E se.