HYMN – IFE RE L’EMI YO SE N’IGBA GBOGBO


IFE RE L’EMI YO SE N’IGBA GBOGBO
Composed by Z. A. Ogunsanya Date: 12/11/2017. During national ministers’ conference.

 1. Ife Re l’emi yo se n’igba gbogbo /2ice.
  Ni owuro, ati l’osan, ni asale
  Ife Re Baba l’emi yo se.

Egbe: Mu mi se’fe Re l’ojo oni o
Mu mi se’fe Re ni ojo gbogbo
Mu mi se’fe Re, k’emi k’o ma segbe.

 1. Ife Re l’emi yo se l’ojo gbogbo /2ice.
  Ni sounde, ni mounde, ni satide
  Ife Re Baba l’emi yo se.

 2. Ife Re l’emi yo se n’ibi gbogbo /2ice.
  Ninu ile, n’ibi ise, n’irin ajo
  Ife Re Baba l’emi yo se.

 3. Ife Re l’emi yo se l’ona gbogbo /2ice.
  Ni ijosin, n’igbeyawo, ni ajogbe
  Ife Re Baba l’emi yo se.

 4. Ife Re l’emi yo se titi d’opin /2ice.
  L’ojo oni, l’ojo ola, l’ojo gbogbo
  Ife Re Baba l’emi yo se.