OLU ORUN E SE O
Composed by Z. A. Ogunsanya, 26/5/2019. In my room, between 3:00am and 4:15am, as the generator went off, and heat made me to be wake.
1. Olu orun E se o /2ice.
Ire ti aye un wa
Lo s’ile babalawo
Ofe ni E fi fun
Olu orun E se o.
Egbe: Eyin ni /2ice.
Gbogbo ope to si
Eyin ni /2ice.
O ye k’a ma yin l’ogo
Olu orun E se o /3ice.
2. Atobiju E se o /2ice.
Ayo ti aye un wa
Ti won se un ru ebo
Ofe ni E fi fun mi
Atobiju E se o.
Egbe: Eyin ni /2ice.
Gbogbo ope to si
Eyin ni /2ice.
O ye k’a ma yin l’ogo
Atobiju E se o /3ice.
3. Oba ogo E se o /2ice.
Abo ti aye un wa
Lo sinu egbe awo
Ofe ni E fi fun mi
Oba ogo E se o.
Egbe: Eyin ni /2ice.
Gbogbo ope to si
Eyin ni /2ice.
O ye k’a ma yin l’ogo
Oba ogo E se o /3ice.