1. Adupe l’owo Re o Baba (Baba Mimo)
Adupe l’owo Re o Omo (Omo Olorun)
Adupe l’owo Re o Emi Mimo
Adupe l’owo Re o Olorun wa (A dupe).
Egbe: Iwo l’Oba t’O ngbo adura
Adura wa o, Baba wa da wa l’ohun
K’o le ri fun wa, gege bi E ti un fe.
- A m’ope wa fun O o Baba (Baba Mimo)
A m’ope wa fun O o Omo (Omo Olorun)
A m’ope wa fun O o Emi Mimo
A m’ope wa fun O o Olorun wa (A dupe). -
Wa da’bo Re bo wa o Baba (Baba Mimo)
Wa da’bo Re bo wa o Omo (Omo Olorun)
Wa da’bo Re bo wa o Emi Mimo
Wa da’bo Re bo wa o Olorun wa (A dupe). -
Wa bukun wa l’oni o Baba (Baba Mimo)
Wa bukun wa l’oni o Omo (Omo Olorun)
Wa bukun wa l’oni o Emi Mimo
Wa bukun wa l’oni o Olorun wa (A dupe). -
Wa f’agbara kun wa o Baba (Baba Mimo)
Wa f’agbara kun wa o Omo (Omo Olorun)
Wa f’agbara kun wa o Emi Mimo
Wa f’agbara kun wa o Olorun wa (A dupe). -
Wa fun wa ni’segun o Baba (Baba Mimo)
Wa fun wa ni’segun o Omo (Omo Olorun)
Wa fun wa ni’segun o Emi Mimo
Wa fun wa ni’segun o Olorun wa (A dupe). -
Wa di wa mu d’opin o Baba (Baba Mimo)
Wa di wa mu d’opin o Omo (Omo Olorun)
Wa di wa mu d’opin o Emi Mimo
Wa di wa mu d’opin o Olorun wa (A dupe).
Composed by Pastor Z. A. Ogunsanya Date: 26/02/2017.
At the beginning of yoruba Bible study, within few minutes.